Read Quran
سُورَةُ النَّاسِ
Suratul An-Naas · 6 ayahs
بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلنَّاسِ ﴿١﴾
114:1Sọ pé: “Mo sá di Olúwa àwọn ènìyàn,
مَلِكِ ٱلنَّاسِ ﴿٢﴾
114:2Ọba àwọn ènìyàn,
إِلَٰهِ ٱلنَّاسِ ﴿٣﴾
114:3Ọlọ́hun àwọn ènìyàn,
مِن شَرِّ ٱلْوَسْوَاسِ ٱلْخَنَّاسِ ﴿٤﴾
114:4níbi aburú (Èṣù) oníròyíròyí, olùsásẹ́yìn (fún ẹni tó bá ń dárúkọ Allāhu.
ٱلَّذِى يُوَسْوِسُ فِى صُدُورِ ٱلنَّاسِ ﴿٥﴾
114:5(Èṣù ni) ẹni tí ó ń kó ròyíròyí sínú àwọn ọkàn ènìyàn.
مِنَ ٱلْجِنَّةِ وَٱلنَّاسِ ﴿٦﴾
114:6(Èṣù náà) wà nínú àwọn àlùjànnú àti àwọn ènìyàn.”
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni