ALMUDEEF TVQuran Channel

Read Quran

سُورَةُ الكَافِرُونَ

Suratul Al-Kaafiroon · 6 ayahs

  1. بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ قُلْ يَٰٓأَيُّهَا ٱلْكَٰفِرُونَ ﴿١﴾

    109:1Sọ pé: “Ẹ̀yin aláìgbàgbọ́,

  2. لَآ أَعْبُدُ مَا تَعْبُدُونَ ﴿٢﴾

    109:2Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún.

  3. وَلَآ أَنتُمْ عَٰبِدُونَ مَآ أَعْبُدُ ﴿٣﴾

    109:3Ẹ̀yin náà kò jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.

  4. وَلَآ أَنَا۠ عَابِدٌۭ مَّا عَبَدتُّمْ ﴿٤﴾

    109:4Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ jọ́sìn fún sẹ́.

  5. وَلَآ أَنتُمْ عَٰبِدُونَ مَآ أَعْبُدُ ﴿٥﴾

    109:5Ẹ̀yin náà kò kú jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.

  6. لَكُمْ دِينُكُمْ وَلِىَ دِينِ ﴿٦﴾

    109:6Tiyín ni ẹ̀sìn yín, tèmi sì ni ẹ̀sìn mi.”

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni