ALMUDEEF TVQuran Channel

Read Quran

سُورَةُ العَصۡرِ

Suratul Al-Asr · 3 ayahs

  1. بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ وَٱلْعَصْرِ ﴿١﴾

    103:1Allāhu fi àkókò ìrọ̀lẹ́ ayé búra.

  2. إِنَّ ٱلْإِنسَٰنَ لَفِى خُسْرٍ ﴿٢﴾

    103:2Dájúdájú ènìyàn wà nínú òfò.

  3. إِلَّا ٱلَّذِينَ ءَامَنُوا۟ وَعَمِلُوا۟ ٱلصَّٰلِحَٰتِ وَتَوَاصَوْا۟ بِٱلْحَقِّ وَتَوَاصَوْا۟ بِٱلصَّبْرِ ﴿٣﴾

    103:3Àyàfi àwọn tó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n ṣe àwọn iṣẹ́ rere, tí wọ́n sọ àsọtẹ́lẹ̀ òdodo láààrin ara wọn, tí wọ́n sì tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ sùúrù láààrin ara wọn.

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni