Read Quran
سُورَةُ الفَلَقِ
Suratul Al-Falaq · 5 ayahs
بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلْفَلَقِ ﴿١﴾
113:1Sọ pé: “Mo sá di Olúwa òwúrọ̀ kùtùkùtù
مِن شَرِّ مَا خَلَقَ ﴿٢﴾
113:2níbi aburú ohun tí Ó dá,
وَمِن شَرِّ غَاسِقٍ إِذَا وَقَبَ ﴿٣﴾
113:3àti níbi aburú òru nígbà tí ó bá ṣóòkùn,
وَمِن شَرِّ ٱلنَّفَّٰثَٰتِ فِى ٱلْعُقَدِ ﴿٤﴾
113:4àti níbi aburú àwọn (òpìdán) tó ń fẹnu fátẹ́gùn túẹ́túẹ́ sínú àwọn ońdè,
وَمِن شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ ﴿٥﴾
113:5àti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara.”
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni